1 Thessalonians 3:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí Oluwa mú kí ìfẹ́ yín sí ara yín ati sí gbogbo eniyan kí ó pọ̀ sí i, kí ó sì túbọ̀ jinlẹ̀, gẹ́gẹ́ bí tiwa ti rí si yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki Oluwa si mã mu nyin bisi i, ki ẹ si mã pọ̀ ninu ifẹ si ọmọnikeji nyin, ati si gbogbo enia, gẹgẹ bi awa ti nṣe si nyin:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A sì béérè pé, kí Ọlọ́run ràn yín lọ́wọ́ tó bẹ́ẹ̀ tí ìfẹ́ yín yóò fi gbòòrò tí yóò sì ṣàn kan olúkúlùkù yín. Èyí yóò jẹ́ àpẹrẹ gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ àwa náà se sàn kan ẹ̀yin náà.