1 Timothy 5:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bá àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ wí ní gbangba, kí ẹ̀rù lè ba àwọn yòókù.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ba awọn ti o ṣẹ̀ wi niwaju gbogbo enia, ki awọn iyokù pẹlu ki o le bẹ̀ru.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bá àwọn tí ó ṣẹ̀ wí níwájú gbogbo ènìyàn, kí àwọn ìyókù pẹ̀lú bà á lè bẹ̀rù.