1 Timothy 5:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bákan náà ni, iṣẹ́ rere a máa hàn sí gbogbo eniyan. Bí wọn kò bá tilẹ̀ tíì hàn, wọn kò ṣe é bò mọ́lẹ̀ títí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ gẹgẹ pẹlu ni iṣẹ rere wà ti nwọn hàn gbangba; awọn iru miran kò si le farasin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ pẹ̀lú ni iṣẹ́ rere wa máa ń hàn gbangba; bí wọn kò tilẹ̀ tíì hàn, wọn kò lè farasin títí.