2 Chronicles 1:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA, Ọlọrun, mú ìlérí tí o ṣe fún Dafidi, baba mi, ṣẹ nisinsinyii, nítorí pé o ti fi mí jọba lórí àwọn eniyan tí wọ́n pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nisisiyi Oluwa Ọlọrun, jẹ ki a mu ọ̀rọ rẹ fun Dafidi baba mi ṣẹ: nitoriti iwọ ti fi mi jọba lori awọn enia ti o pọ̀ bi erupẹ ilẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nísinsinyìí OLÚWA Ọlọ́run, jẹ́ kí ìlérí rẹ sí baba à mi Dáfídì di mímúsẹ, nítorí ìwọ ti fi mí jẹ ọba lóri àwọn ènìyàn tí ó pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀.