2 Chronicles 10:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Láti ìgbà náà lọ ni àwọn ọmọ Israẹli ti ń bá ilé Dafidi ṣọ̀tẹ̀ títí di òní olónìí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni Israeli si ya kuro lọdọ ile Dafidi titi o fi di oni yi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni Ísírẹ́lì sì wà ní ìsọ̀tẹ̀ lórí ilé Dáfídì títí fi di òní yìí.
Recommended Reading