2 Chronicles 12:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó gba gbogbo ìlú olódi Juda títí ó fi dé Jerusalẹmu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si kọ́ awọn ilu olodi ti iṣe ti Juda, o si wá si Jerusalemu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó fi agbára mú àwọn ìlú ààbò ti Júdà, pẹ̀lú wá sí Jérúsálẹ́mù bí ó ti jìnnà tó.