2 Chronicles 13:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo nǹkan yòókù ti Abija ṣe ní àkókò ìjọba rẹ̀, ati ohun tí ó sọ, ni a kọ sinu Ìwé Ìtàn wolii Ido.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati iyokù iṣe Abijah, ati iwà rẹ̀, ati iṣẹ rẹ̀, a kọ wọn sinu iwe-itumọ Iddo, woli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti ìyókù ìṣe Ábíjà, àti ìwà rẹ̀, àti iṣẹ́ rẹ̀, a kọ wọ́n sínú ìwé ìtumọ̀ Ididì, wòlíì Ídò.