2 Chronicles 17:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ó ní ilé tí wọn ń kó nǹkan pamọ́ sí ní àwọn ìlú ńláńlá Juda. Ó sì ní àwọn akọni ọmọ ogun ní Jerusalẹmu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ni iṣura pupọ ni ilu Juda; ati awọn jagunjagun, awọn alagbara akọni ọkunrin ti o wà ni Jerusalemu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì ní ìṣúra ní ìlu Júdà. Ó sì tún ní àwọn alágbára jagunjagun akọni ọkùnrin ní Jérúsálẹ́mù.