2 Chronicles 17:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Igbákejì ni Jehosabadi; òun náà ní ọ̀kẹ́ mẹsan-an (180,000) ọmọ ogun tí wọ́n ti dira ogun, lábẹ́ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati atẹle rẹ̀ ni Jehosabadi, ati pẹlu rẹ̀ ọkẹ mẹsan, ti o mura silẹ de ogun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àtẹ̀lé Jéhósábádì, pẹ̀lú ọ̀kẹ́ mẹ́sàn án (180,000) jagunjagun ọkùnrin múra sílẹ̀ fún ogun.