2 Chronicles 17:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó kó àwọn ọmọ ogun sí gbogbo àwọn ìlú olódi Juda, ó yan olórí ogun fún wọn ní ilẹ̀ Juda ati ní ilẹ̀ Efuraimu tí Asa baba rẹ̀ gbà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si fi ogun sinu gbogbo ilu olodi Juda, o si fi ẹgbẹ-ogun si ilẹ Juda ati sinu ilu Efraimu wọnni, ti Asa baba rẹ̀ ti gbà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì fi ogun sínú gbogbo ìlú olódi Júdà ó sì kó ẹgbẹ́ ológun ní Júdà àti nínú ìlú Éfúráímù tí baba rẹ̀ ti gbà.