2 Chronicles 18:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mikaya ní, “OLUWA ni ó mú kí àwọn wolii rẹ wọnyi máa sọ àsọtẹ́lẹ̀ èké, ṣugbọn àjálù burúkú ni OLUWA ti pinnu pé yóo dé bá ọ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ nisisiyi, kiyesi i, Oluwa ti fi ẹmi eke si ẹnu gbogbo awọn woli rẹ wọnyi, Oluwa si ti sọ ibi si ọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Bẹ́ẹ̀ ni nísinsìn yìí OLÚWA ti fi ẹ̀mí èké sí ẹnu àwọn wòlíì rẹ. OLÚWA sì ti sọ ibi sí ọ.”