2 Chronicles 2:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Solomoni ọba pinnu láti kọ́ tẹmpili níbi tí àwọn eniyan yóo ti máa sin OLUWA ati láti kọ́ ààfin fún ara rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
SOLOMONI si pinnu rẹ̀ lati kọ́ ile kan fun orukọ Oluwa, ati ile kan fun ijọba rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sólómónì pinnu láti kọ́ ilé fún orúkọ OLÚWA àti ilé kan fún ìjọba rẹ̀