2 Chronicles 2:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kò sí ẹni tí ó lè kọ́ ilé fún un, nítorí pé ọ̀run, àní ọ̀run tí ó ga jùlọ, kò le è gbà á. Kí ni mo jẹ́ tí n óo fi kọ́ ilé fún un, bíkòṣe pé kí n kọ́ ibi tí a óo ti máa sun turari níwájú rẹ̀?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn tani to lati kọ́ ile fun u, nitori ọrun ati ọrun awọn ọrun kò le gbà a? tali emi ti emi iba kọ́le fun u, bikòṣe kiki ati sun ẹbọ niwaju rẹ̀?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ta ni ó le è kọ́ ilé fún OLÚWA, níwọ̀n ìgbà tí àwọn ọ̀run, àní ọ̀run tí ó ga jùlọ, kò ti le è gbà á? Ta ni èmi nígbà náà láti kọ́ ilé fún OLÚWA, àyàfi ibi kan fún sísun ẹbọ níwájú rẹ̀?