2 Chronicles 2:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
láti tọ́jú ọpọlọpọ igi, nítorí pé ilé tí mo fẹ́ kọ́ yóo tóbi, yóo sì jọjú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ani lati pèse ìti-igi lọpọlọpọ silẹ fun mi: nitori ile na ti emi mura lati kọ́ tobi, o si ya ni lẹnu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti pèsè ọ̀pọ̀ igi rírẹ́ fún mi, nitorí ilé OLÚWA tí mo kọ́ gbọdọ̀ tóbi kí o sì lógo púpọ̀.