2 Chronicles 20:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n dé Jerusalẹmu, wọ́n wọ inú tẹmpili lọ, pẹlu ìró hapu, ati ti dùùrù ati ti fèrè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si wá si Jerusalemu pẹlu ohun-elo orin, ati duru ati ipè si ile Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì wọ Jérúsálẹ́mù, wọ́n sì lọ sí ilé OLÚWA pẹ̀lú ohun èlò orin àti dùùrù àti ipè.