2 Chronicles 20:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ̀rù ba Jehoṣafati gidigidi, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí wá ojú OLUWA, ó kéde jákèjádò ilẹ̀ Juda pé kí wọ́n gbààwẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jehoṣafati si bẹ̀ru, o si fi ara rẹ̀ si ati wá Oluwa, o si kede àwẹ ja gbogbo Juda.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ìdágìrì, Jéhóṣáfátì pinnú láti wádìí lọ́wọ́ OLÚWA, ó sì kéde ààwẹ̀ kíákíá fún gbogbo Júdà.