2 Chronicles 22:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí Atalaya, ìyá Ahasaya rí i pé ọmọ òun ti kú, ó bẹ̀rẹ̀ sí pa gbogbo ìran ọba ní Juda.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nigbati Ataliah, iya Ahasiah, ri pe ọmọ on kú, o dide o si run gbogbo iru ọmọ ijọba ile Judah.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí Ataláyà ìyá Áhásáyà ríi wí pé ọmọkùnrin rẹ̀ ti kú, ó tẹ̀ṣíwájú láti pa gbogbo ìdílé ọba ti ilẹ̀ Júdà run.