2 Chronicles 23:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n lọ káàkiri gbogbo ilẹ̀ Juda, wọ́n lọ kó àwọn Lefi ati àwọn baálé baálé gbogbo ní Israẹli wá sí Jerusalẹmu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si lọ kakiri ni Juda, nwọn si kó awọn ọmọ Lefi jọ lati inu gbogbo ilu Juda, ati olori awọn baba ni Israeli, nwọn si wá si Jerusalemu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n lọ sí gbogbo Júdà, wọ́n sì pe àwọn ará Léfì àti àwọn olórí àwọn ìdílé àwọn ará Ísírẹ́lì láti gbogbo àwọn ìlú jọ. Nígbà tí wọ́n wá sí Jérúsálẹ́mù.