2 Chronicles 24:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọmọ ọdún meje ni Joaṣi nígbà tí ó gorí oyè, ó sì jọba ní Jerusalẹmu fún ogoji ọdún. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Sibaya, ará Beeriṣeba.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
ẸNI ọdun meje ni Joaṣi nigbati o bẹ̀rẹ si ijọba, o si jọba ogoji ọdun ni Jerusalemu. Orukọ iya rẹ̀ si ni Sibia ti Beer-ṣeba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jóásì jẹ́ ọmọ ọdún méje nígbà tí ó jẹ ọba, ó sì jọba ní Jérúsálẹ́mù fún ogójì ọdún. Orúkọ ìya rẹ̀ ni Ṣíbíà ti Béríṣébà.