2 Chronicles 24:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo àwọn ìjòyè ati gbogbo eniyan fi tayọ̀tayọ̀ mú owó orí wọn wá, wọ́n ń sọ ọ́ sinu àpótí náà títí tí ó fi kún.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn ijoye ati gbogbo awọn enia si yọ̀, nwọn si mu wá, nwọn fi sinu apoti na, titi o fi kún.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn ènìyàn mú gbogbo ìdá owó ti wọn wá pẹ̀lú ìdùnnú, wọ́n ń jù ú sínú àpótí títí tí ó fi kún.