2 Chronicles 24:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọba ati Jehoiada gbé owó náà fún àwọn tí wọn ń ṣe àkóso iṣẹ́ ilé OLUWA, wọ́n gba àwọn ọ̀mọ̀lé, àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà ati àwọn alágbẹ̀dẹ irin ati ti bàbà, láti tún ilé OLUWA ṣe.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ọba ati Jehoiada fi i fun iru awọn ti nṣiṣẹ ile Oluwa, nwọn si fi gbà àgbaṣe awọn oniṣọ̀nà okuta, ati awọn gbẹnàgbẹna, lati tun ile Oluwa ṣe, ati pẹlu awọn alagbẹdẹ irin, ati idẹ, lati tun ile Oluwa ṣe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọba àti Jéhóiádà fi fún àwọn ọkùnrin náà tí ó gbé iṣẹ́ náà jáde ti a bèrè fún ilé OLÚWA. Wọ́n fi owó gba ẹni tí ń fi òkúta mọ ilé àti àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà láti kọ́ ilé OLÚWA padà, àti àwọn òsìsẹ́ pẹ̀lú irin àti idẹ láti tún ilé OLÚWA ṣe.