2 Chronicles 24:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn wọ́n dìtẹ̀ mọ́ ọn. Lẹ́yìn náà, ọba pàṣẹ pé kí wọn sọ ọ́ lókùúta pa ninu gbọ̀ngàn ilé OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si di rikiṣi si i, nwọn si sọ ọ li okuta nipa aṣẹ ọba li agbala ile Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n wọ́n dìtẹ̀ sí i, àti nípa àṣẹ ọba, wọ́n sọ ọ́ lókúta pa nínú àgbàlá ààfin ilé OLÚWA