2 Chronicles 24:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, ọba pàṣẹ pé kí wọ́n ṣe àpótí kan tí àwọn eniyan yóo máa sọ owó sí, kí wọ́n sì gbé e sí ẹnu ọ̀nà ilé OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọba si paṣẹ, nwọn si kàn apoti kan, nwọn si fi si ita li ẹnu-ọ̀na ile Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nípasẹ̀ ọba, a ṣe àpótí wọ́n sì gbé e sí ìta, ní ẹnu ọ̀nà ilé OLÚWA.