2 Chronicles 25:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n fi ẹṣin gbé òkú rẹ̀ wá sí Jerusalẹmu, wọ́n sì sin ín sí ìlú Dafidi ní ibojì àwọn baba rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si mu u wá lori ẹṣin, nwọn si sìn i pẹlu awọn baba rẹ̀ ni ilu Dafidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A gbé e padà pẹ̀lú ẹsin. A sì sin ín pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀ ní ìlú ńlá ti Júdà.