2 Chronicles 26:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn Asaraya, alufaa, wọlé lọ bá a pẹlu àwọn ọgọrin alufaa tí wọ́n jẹ́ akọni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Asariah, alufa si wọle tọ̀ ọ lọ ati ọgọrin alufa Oluwa pẹlu rẹ̀, awọn alagbara,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ásáríyà àlùfáà pẹ̀lú àwọn ọgọ́rin alágbára àlùfáà OLÚWA mìíràn sì tẹ̀lée.