2 Chronicles 29:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ṣíṣe ní tẹmpili nìwọ̀nyí: láti inú ìdílé Kohati: Mahati, ọmọ Amasai, ati Joẹli, ọmọ Asaraya; láti inú ìdílé Merari: Kiṣi, ọmọ Abidi ati Asaraya, ọmọ Jahaleleli; láti inú ìdílé Geriṣoni: Joa, ọmọ Sima ati Edẹni, ọmọ Joa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana li awọn ọmọ Lefi dide, Mahati, ọmọ Amasai, ati Joeli, ọmọ Asariah, ninu awọn ọmọ Kohati: ati ninu awọn ọmọ Merari, Kiṣi, ọmọ Abdi, ati Asariah, ọmọ Jehaleeli: ati ninu awọn ọmọ Gerṣoni, Joah, ọmọ Simma, ati Edeni, ọmọ Joah:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà àwọn ọmọ Léfì wọ̀nyí múra láti ṣe iṣẹ́: nínú àwọn ọmọ Kóhátì, Máhátì ọmọ Ámásà: àti jóẹ́lì ọmọ Ásáríyà; nínú àwọn ọmọ Mérárì, Kíṣì ọmọ Ábídì àti Ásáríyà ọmọ Jéháiéíèlì; nínú àwọn ọmọ Gésónì, Jóà, ọmọ símà àti Édẹ́nì ọmọ Jóà;