2 Chronicles 29:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Láti inú ìdílé Elisafani: Ṣimiri ati Jeueli; láti inú ìdílé Asafu: Sakaraya ati Matanaya,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ninu awọn ọmọ Elisafani, Ṣimri ati Jegieli: ati ninu awọn ọmọ Asafu, Sekariah ati Mattaniah.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nínú àwọn ọmọ Élisáfánì, Ṣímírì àti Jégíèlì; nínú àwọn ọmọ Ásáfù, Sékáríà àti Mátaníyà;