2 Chronicles 29:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
láti inú ìdílé Hemani: Jeueli ati Ṣimei; láti inú ìdílé Jedutuni: Ṣemaaya ati Usieli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ninu awọn ọmọ Hemani, Jehieli ati Ṣimei: ati ninu awọn ọmọ Jedutuni, Ṣemaiah ati Ussieli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nínú àwọn ọmọ Hémánì, Jéhíélì àti Ṣíméhì; nínú àwọn ọmọ Jédútùnì, Ṣémáíà àti Húsíélì.