2 Chronicles 30:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo wọn tún pinnu láti pa àjọ náà mọ́ fún ọjọ́ meje sí i, wọ́n sì fi tayọ̀tayọ̀ ṣe é.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo ijọ na si gbìmọ lati pa ọjọ meje miran mọ́: nwọn si fi ayọ̀ pa ọjọ meje miran mọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo ìjọ náà sì gbìmọ̀ láti pa ọjọ́ méje mìíràn mọ́: wọ́n sì fi ayọ̀ pa ọjọ́ méje mìíràn mọ́.