2 Chronicles 30:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo Jerusalẹmu kún fún ayọ̀ nítorí kò tíì tún sí irú rẹ̀ mọ́ láti ìgbà Solomoni, ọmọ Dafidi, ọba Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃li ayọ̀ nla si wà ni Jerusalemu: nitori lati ọjọ Solomoni, ọmọ Dafidi, ọba Israeli, iru eyi kò sí ni Jerusalemu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni ayọ̀ ńlá sì wà ní Jérúsálẹ́mù: nítorí láti ọjọ́ Sólómónì, ọmọ Dáfídì, ọba Ísírẹ́lì, irú èyí kò sí ní Jérúsálẹ́mù.