2 Chronicles 30:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìpinnu yìí dára lójú ọba ati gbogbo ìjọ eniyan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọran na si tọ́ loju ọba ati loju gbogbo ijọ-enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọ̀ràn náà sí tọ́ lójú ọba àti lójú gbogbo ìjọ ènìyàn.
Recommended Reading