2 Chronicles 31:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Hesekaya bá pàṣẹ pé kí wọ́n tọ́jú àwọn yàrá tó wà ninu ilé OLUWA, wọ́n bá ṣe ìtọ́jú wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Hesekiah paṣẹ lati pèse iyàrá-iṣura ni ile Ọlọrun; nwọn si pèse wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Heṣekáyà pàsẹ láti tọ́jú àwọn yàrá ìpamọ́ nínú ilé OLÚWA, wọ́n sì ṣe èyí.