2 Chronicles 33:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọmọ ọdún mejila ni Manase nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún marundinlọgọta.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
ẸNI ọdun mejila ni Manasse, nigbati o bẹ̀rẹ si ijọba, o si jọba ọdun marundilọgọta ni Jerusalemu:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mánásè jẹ́ ọmọ ọdún Méjìlá nígbà tí ó di ọba. Ó sì jọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún márùndínlọ́gọ́ta.