2 Chronicles 33:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí ó yá, àwọn ọ̀gágun rẹ̀ dìtẹ̀ mọ́ ọn, wọ́n sì pa á ní ààfin rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn iranṣẹ rẹ̀ si di rikiṣi si i, nwọn si pa a ni ile rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn onísẹ́ Ámónì dìtẹ̀ síi. Wọ́n sì pa á ní ààfin rẹ̀
Recommended Reading