2 Chronicles 33:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó tẹ́ pẹpẹ sinu gbọ̀ngàn meji tí ó wà ninu tẹmpili, wọ́n sì ń bọ àwọn ìràwọ̀ ati gbogbo ohun tí ó wà lójú ọ̀run níbẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si tẹ́ pẹpẹ fun gbogbo ogun ọrun li àgbala mejeji ile Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú ààfin méjèèje ti ilé OLÚWA, ó kọ́ àwọn pẹpẹ fún gbogbo àwọn ogun ọ̀run