2 Chronicles 34:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí wọn ń kó owó tí àwọn eniyan ti mú wá sinu ilé OLUWA jáde, Hilikaya, alufaa rí ìwé òfin OLUWA tí Ọlọrun fún Mose.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati nwọn si mu owo na ti a mu wá sinu ile Oluwa jade wá, Hilkiah alufa, ri iwe ofin Oluwa ti a ti ọwọ Mose kọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí wọ́n mú owó náà tí wọ́n mú wá sí ilé OLÚWA, Hílkíà àlùfáà sì rí ìwe òfin OLÚWA tí a ti fi fún-un láti ọwọ́ Mósè.