2 Chronicles 35:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní ọdún kejidinlogun ìjọba Josaya ni wọ́n ṣe Àjọ Ìrékọjá yìí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọdun kejidilogun ijọba Josiah li a pa irekọja yi mọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àjọ ìrékọjá yìí ni a ṣe ìrántí ní ọdún kejìdínlogún ìjọba Jósíà