2 Chronicles 35:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àkọsílẹ̀ gbogbo àwọn nǹkan yòókù tí Josaya ṣe ati iṣẹ́ rere rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ sinu ìwé òfin OLUWA,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati iyokú iṣe Josiah, ati ìwa rere rẹ̀, gẹgẹ bi eyiti a ti kọ ninu ofin Oluwa,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìyòókù iṣẹ́ ìjọba Jósíà àti ìwà rere rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí èyí tí a ti kọ sínu ìwé òfin OLÚWA.