2 Chronicles 36:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nebukadinesari, ọba Babiloni, kó ninu àwọn ohun èlò ilé OLUWA lọ sí Babiloni, ó kó wọn sinu ààfin rẹ̀ ní Babiloni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nebukadnessari kó ninu ohun-elo ile Oluwa lọ si Babeli pẹlu, o si fi wọn sinu ãfin rẹ̀ ni Babeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nebukadínésárì pẹ̀lú mú-un lọ sí Bábílónì, ohun èlò láti ilé OLÚWA, ó sì mú wọn lọ sí ààfin tirẹ̀ níbẹ̀.