2 Chronicles 4:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn nǹkan tí Solomoni ṣe pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí a kò fi mọ ìwọ̀n idẹ tí ó lò.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi ni Solomoni ṣe gbogbo ohun-elo wọnyi li ọ̀pọlọpọ: nitori ti a kò le mọ̀ ìwọn idẹ na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo nǹkan wọ̀nyí tí Sólómónì ṣe ní iye lórí púpọ̀ tí a kò le mọ ìwọ̀n iye idẹ tí ó wọ̀n.