2 Chronicles 4:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọ̀pá ati fìtílà tí wọ́n fi ojúlówó wúrà ṣe láti máa jò níwájú ibi mímọ́ jùlọ gẹ́gẹ́ bí a ti pa á láṣẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọpa-fitila pẹlu ati fitila wọn, ki nwọn ki o ma jo gẹgẹ bi aṣẹ niwaju ibi-mimọ́-jùlọ, jẹ wura daradara.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọ̀pá fìtílà tí a fi ojúlówó wúrà ṣe pẹ̀lú fìtílà wọn kí wọn lè máa jó gẹ́gẹ́ bí àṣẹ ní iwájú ibi mímọ́ jùlọ gẹ́gẹ́ bí a ṣe fi lélẹ̀;