2 Chronicles 4:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó fi wúrà tí ó dára jùlọ ṣe àwọn òdòdó, àwọn fìtílà ati àwọn ẹ̀mú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati itanna, ati fitila ati ẹ̀mu li o fi wura ṣe; gbogbo eyi ni wura daradara;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pẹ̀lú ìtànná wúrà àti fìtílà àti ẹ̀mú (ni ó jẹ́ kìkìdá wúrà tí ó gbópọn);