2 Chronicles 5:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
tóbẹ́ẹ̀ tí àwọn alufaa kò fi lè ṣe iṣẹ́ ìsìn wọn, nítorí ògo OLUWA tí ó kún ilé Ọlọrun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Tobẹ̃ ti awọn alufa kò le duro lati ṣiṣẹ ìsin nitori awọsanmọ na: nitori ogo Oluwa kún ile Ọlọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tó bẹ́ẹ̀ tí àwọn àlùfáà kò leè ṣiṣẹ́ ìsìn wọn nítorí ìkùku náà, nítorí ògo OLÚWA kún inú tẹ́ḿpìlì Ọlọ́run.