2 Chronicles 5:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí àwọn àgbààgbà péjọ tán, àwọn ọmọ Lefi gbé àpótí náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn àgbagba Israeli si wá; awọn ọmọ Lefi si gbé apoti-ẹri na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn àgbààgbà Isirẹ́lì sì wá, àwọn ọmọ Léfì gbé àpótí ẹ̀rí OLÚWA.