2 Chronicles 5:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn alufaa gbé àpótí majẹmu OLUWA wá sí ààyè rẹ̀ ninu tẹmpili ní ibi mímọ́ jùlọ, wọ́n gbé e sí abẹ́ àwọn ìyẹ́ kerubu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn alufa si gbé apoti-ẹri ti majẹmu Oluwa wá si ipò rẹ̀, si ibi-idahùn ile na, sinu ibi-mimọ́-jùlọ, labẹ iyẹ awọn kerubu:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni àwọn àlùfáà gbé àpótí ẹ̀ri ti májẹ̀mú OLÚWA wá sí ipò rẹ̀, sí ibi inú lọ́hùn ún ilé OLÚWA, ibi mímọ́ jùlọ, wọ́n gbé e sí abẹ́ ìyẹ́ àwọn kérúbù.