2 Chronicles 6:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Solomoni ọba ní, “OLUWA, o ti sọ pé o óo máa gbé inú òkùnkùn biribiri.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
NIGBANA ni Solomoni wipe, Oluwa ti wipe, on o ma gbe inu òkunkun biribiri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Sólómonì wí pé, “OLÚWA ti sọ wí pé òun yóò máa gbé nínú ìkùku tí ó ṣú biribiri;