2 Chronicles 6:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo ti gbé àpótí ẹ̀rí sibẹ, inú rẹ̀ sì ni majẹmu tí OLUWA bá àwọn eniyan Israẹli dá wà.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ninu rẹ̀ ni mo fi apoti-ẹri na si, ninu eyiti majẹmu Oluwa wà, ti o ba awọn ọmọ Israeli dá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Níbẹ̀ ni èmi sì gbé àpótí ẹ̀rí OLÚWA sí, nínú èyí ti májẹ̀mú ti OLÚWA bá àwọn Ísirẹ́lì ènìyàn mi dá wà.”