2 Chronicles 7:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn, bí ìwọ bá tẹ̀lé ìlànà mi gẹ́gẹ́ bí Dafidi baba rẹ ti ṣe, tí o pa gbogbo òfin mi mọ́, tí o tẹ̀lé ìlànà ati àṣẹ mi,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati iwọ, bi iwọ o ba rìn niwaju mi bi Dafidi, baba rẹ ti rìn, ki o si ṣe gẹgẹ bi gbogbo eyiti mo ti pa li aṣẹ fun ọ, bi iwọ o ba si ṣe akiyesi aṣẹ mi ati idajọ mi;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ní ti bí ìwọ bá rìn níwájú mi gẹ́gẹ́ bí Dáfídì baba rẹ ti ṣe, tí o sì ṣe gbogbo ohun tí mo palásẹ, tí ìwọ sì ṣe àkíyèsí àṣẹ mi láti ọ̀run: