2 Chronicles 8:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn olórí lára àwọn òṣìṣẹ́ Solomoni jẹ́ igba ati aadọta (250), àwọn ni wọ́n ń ṣe àkóso àwọn tí wọn ń ṣiṣẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn wọnyi li olori awọn alaṣẹ Solomoni ọba, adọtalerugba ti nṣakoso lori awọn enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì tún jẹ́ olórí alásẹ fún ọba Sólómónì àádọ́ta ó lé nígba àwọn alákòóso lórí àwọn ènìyàn (250).