2 Chronicles 8:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bẹ́ẹ̀ ni Solomoni ṣe ṣe gbogbo iṣẹ́ tí ó ṣe láti ìgbà tí ó ti fi ìpìlẹ̀ ilé OLUWA lélẹ̀ títí di ìgbà tí ó parí iṣẹ́ náà patapata.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo iṣẹ Solomoni li a ti pese silẹ bayi de ọjọ ifi-ipilẹ ile Oluwa le ilẹ titi o fi pari. A si pari ile Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo iṣẹ́ Sólómónì ni a gbé jáde láti ọjọ́ ìfi ìpìlẹ̀ ilé OLÚWA lé lẹ̀ títí ó fi di ọjọ́ ìparí. Bẹ́ẹ̀ ni ilé OLÚWA sì parí.